Home2023 ElectionsJust In: Traditional Yoruba Incantation For The 2023 Elections And Victory Of...

Just In: Traditional Yoruba Incantation For The 2023 Elections And Victory Of Asiwaju Tinubu.

Traditional Yoruba Incantation For The 2023 Elections And Victory Of Asiwaju Tinubu. Can Be Recited By All.

Iwaju opon o gbo,
Eyin opon o gba,
Olumu Otun, Olukanran Osi,
Aarin opon Ita Orun,
O different fun Bola Ahmed Tinubu ,
Negative awon PDP, NNPP, Labour Party pejo ni ilu Abuja ati nibi gbogbo,
Won ni ki Bola Ahmed Tinubu maa so wipe:
Osalala loruko ti a pe aye
Obelisk Jana loruko Esu Odara,
Adifa fun rikisi awon aje Abuja, ati awon aje ibiza gbogbo,
Imo enini kii dojo ale,
Emo ajao ki ja,
Ajaro ni ti adan,
Eja kii sere erupe dojo ale,
Ajantuka ni ti agbaarin,
Ibi ti Ojo ba ti ba Ojo,
Ibe lo maa pasi,
Gbogbo abamoda won,efufulele
Maa dawon nu, Efufulele.
Sugbon nipa ti Bola Ahmed Tinubu,
Kenke loruko ti a npori,
Atari pakata loruko ona.

Ona la, Bola Ahmed Tinubu fe wo Aso Rock ni February 2023.
Ona laaaaaaaaaaaa!!!!!!

Aboru boye ni tifa Ooooooo
In shaa Allah, Loruko Jesu.
Awa lo kan, A ma digbo, A ma wole lola Olodumare, lola Ifa, lola awon to di ile aiye mu, lola Oluweri magbojo, Sango Asakayeriyeri, Ogun Lakaiye Osinmale Koriko Odo Tinru mirinmirin, igbe lehin eni a’n da loro, Obatala Obatarisa, awon Osi, irumole, alale, orissa ile yoruba, isese a gbe wa Oooooo. Ki ona la fun Bola Ahmed Tinubu ni ibo osu yi Ooooo.
Awa lokan Oooooo.

The National Patriots
Dr. Hameeda
National Coordinator.

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here

- Advertisement -spot_img
Must Read
Related News
- Advertisement -spot_img